Léfítíkù 14:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àlùfáà yóò pàṣẹ kí a yọ àwọn òkúta tí àrùn náà ti bàjẹ́ kúrò kí a sì kó wọn dànù sí ibi tí a kà sí àìmọ́ lẹ́yìn ìlú.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:37-42