Léfítíkù 14:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àlùfáà yóò padà wá yẹ ilé náà wò ní ọjọ́ keje. Bí àrùn náà bá ti tàn ká ara ògiri.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:29-42