Léfítíkù 14:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àlùfáà yóò sì rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀: yóò ṣe ètùtù fún ẹni tí a ó wẹ̀ kúrò nínú àìmọ́ rẹ̀, lẹ́yìn náà àlùfáà yóò pa ẹran ọrẹ ẹbọ sísun.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:14-22