Léfítíkù 14:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì rú u lórí pẹpẹ pẹ̀lú ọrẹ ohun jíjẹ, yóò sì ṣe ètùtù fún un: Òun yóò sì di mímọ́.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:10-21