Léfítíkù 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àlùfáà yóò fi òróró tí ó kù ní àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀ ra orí ẹni tí a ó wẹ̀ mọ́, yóò sì ṣe ètùtù fún un níwájú Olúwa.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:14-24