Léfítíkù 14:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àlùfáà yóò mú lára òróró tí ó kù ní àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀ yóò fi sí etí ọ̀tún, àtàǹpàkò ọwọ́ ọ̀tún àti àtàǹpàkò ẹsẹ̀ ọ̀tún ẹni tí à ó wẹ̀ mọ́.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:16-19