Léfítíkù 14:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì ti ìka ìfábẹ̀ ọ̀tún rẹ̀ bọ inú òróró àtẹ́lẹwọ́ rẹ̀, yóò sì wọ́n díẹ̀ nínú rẹ̀ níwájú Olúwa nígbà méje.

Léfítíkù 14

Léfítíkù 14:6-21