Jóṣúà 24:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n mo mú Ábúráhámù baba yín kúrò ní ìkọjá odò mo sì ṣe amọ̀nà rẹ̀ ni gbogbo Kénánì, mo sì fún ní àwọn ọmọ púpọ̀. Mo fún ní Ísáákì,

Jóṣúà 24

Jóṣúà 24:1-8