Jóṣúà 24:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣúà sì sọ fun gbogbo ènìyàn pé, “Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì, wí: ‘Nígbà kan rí àwọn baba ńlá yín Térà bàbá Ábúráhámù àti Náhórì ń gbé ní ìkọjá odò, wọ́n sì sin àwọn òrìṣà.

Jóṣúà 24

Jóṣúà 24:1-10