Jóṣúà 24:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì fún ní Ísáákì, mo fún ní Jákọ́bù àti Ísáù, mo sì fún Ísáù ní ilẹ̀ orí òkè Séírì, Ṣùgbọ́n Jákọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀ sọ̀ kalẹ̀ lọ sí Éjíbítì.

Jóṣúà 24

Jóṣúà 24:1-11