Jóṣúà 18:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti òkè tí ó kọjú sí Bẹti-Hórónì ní gúsù ààlà náà yà sí gúsù ní ìhà ìwọ̀-oòrùn, ó sì jáde sí Kiriati-Báálì (tí í ṣe Kiriati-Jéárímù), ìlú àwọn ènìyàn Júdà. Èyí ni ìhà ìwọ̀-oòrùn.

Jóṣúà 18

Jóṣúà 18:8-15