Jóṣúà 18:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ibẹ̀ ààlà náà tún kọjá lọ sí ìhà gúsù ní ọ̀nà Lúsì, (èyí ni Bẹ́tẹ́lì) ó sìdé Afaroti-Ádárì, ní orí òkè tí ó wà ní gúsù Bẹti-Hórónì

Jóṣúà 18

Jóṣúà 18:3-21