Jóṣúà 18:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìhà gúsù bẹ̀rẹ̀ ní ìpẹ̀kun Kiriati-Jéárímù ní ìwọ̀-oòrùn, ààlà náà wà ní ibi ìsun omi Nẹ́fítóà.

Jóṣúà 18

Jóṣúà 18:11-17