Jóṣúà 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè ìránṣẹ́ Olúwa àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì borí wọn. Mósè ìránṣẹ́ Olúwa sì fi ilẹ̀ wọn fún àwọn ẹ̀yà Rúbẹ́nì, àwọn ẹ̀yà Gádì àti ìdajì ẹ̀yà Mánásè kí ó jẹ́ ohun ìní wọn.

Jóṣúà 12

Jóṣúà 12:4-7