Jóṣúà 12:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó se àkóso ní orí Okè Hámónì, Sálékà, Básánì títí dé ààlà àwọn ènìyàn Gésúrì àti Máákà, àti ìdajì Gílíádì dé ààlà Síhónì ọba Hésíbónì.

Jóṣúà 12

Jóṣúà 12:1-7