Jóṣúà 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti agbégbé Ógù ọba Básánì,ọ̀kan nínú àwọn tí ó kù nínú àwọn ará Ráfíátì, ẹni tí ó jọba ní Ásítarótù àti Édírì.

Jóṣúà 12

Jóṣúà 12:1-7