Jóòbù 11:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ó sì dùbúlẹ̀ pẹ̀lú, kì yóò sì sí ẹni tí yóò dẹ́rùbà ọ́,àní ènìyàn yóò máa wá ojú rere rẹ.

Jóòbù 11

Jóòbù 11:15-20