Jóòbù 11:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ó sì wà láìléwu, nítorí pé ìrètí wà;àní ìwọ ó rin ilé rẹ wò, ìwọ ó sì sinmi ní àlàáfíà.

Jóòbù 11

Jóòbù 11:15-19