Jóòbù 1:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú gbogbo èyí Jóòbù kò ṣẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò sì fi òmùgọ̀ pe Ọlọ́run lẹ́jọ́.

Jóòbù 1

Jóòbù 1:19-22