Jóòbù 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wí pé:“Ní ìhòòhò ní mo ti inú ìyá mi jáde wá,ni ìhòòhò ní èmi yóò sì tún padà lọ síbẹ̀. Olúwa fi fún ni, Olúwa sì gbà á lọ,ìbùkún ni fún orúkọ Olúwa.”

Jóòbù 1

Jóòbù 1:15-22