Jòhánù 14:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù dá wọn lóhùn pé, “Èmi ni ọ̀nà, òtítọ́ àti ìyè: kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè wá sọ́dọ̀ Baba, bí kò ṣe nípaṣẹ̀ mi.

Jòhánù 14

Jòhánù 14:1-12