Jòhánù 14:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tómásì wí fún un pé, “Olúwa, a kò mọ ibi tí ìwọ ń lọ, a ó ha ti ṣe mọ ọ̀nà náà?”

Jòhánù 14

Jòhánù 14:1-13