Jòhánù 14:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbáṣe pé ẹ̀yin ti mọ̀ mí, ẹ̀yin ìbá ti mọ Baba mi pẹ̀lú: láti ìsinsinyìí lọ ẹ̀yin mọ̀ ọ́n, ẹ sì ti rí i.”

Jòhánù 14

Jòhánù 14:2-11