Jòhánù 14:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ má ṣe jẹ́ kí ọkàn yín kí ó dàrú: ẹ gba Ọlọ́run gbọ́, kí ẹ sì gbà mí gbọ́ pẹ̀lú.

Jòhánù 14

Jòhánù 14:1-3