Jòhánù 14:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ilé Baba mi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ibùgbé ni ó wà: ìbá má ṣe bẹ́ẹ̀, èmi ìbá tí sọ fún yín. Èmi ń lọ láti pèṣè àyè sílẹ̀ fún yín.

Jòhánù 14

Jòhánù 14:1-9