Jòhánù 13:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù da lóhùn wí pé, “Ìwọ ó ha fi ẹ̀mí rẹ lélẹ̀ nítorí mi? Lóòótọ́ lóòótọ́ ni mo wí fún ọ, àkùkọ kì yóò kọ, kí ìwọ kí ó tó ṣẹ́ mi nígbà mẹ́ta!

Jòhánù 13

Jòhánù 13:29-38