Jòhánù 13:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù wí fún un pé, “Olúwa èése tí èmi kò fi le tọ̀ ọ́ nísinsìn yìí? Èmi ó fi ẹ̀mi mi lélẹ̀ nítorí rẹ.”

Jòhánù 13

Jòhánù 13:34-38