Jòhánù 13:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Símónì Pétérù wí fún un pé, “Olúwa, níbo ni ìwọ ń lọ?”Jésù dá a lóhùn pé, “Níbi tí èmi ń lọ, ìwọ kì yóò lè tọ̀ mí nísinsin yìí; ṣùgbọ́n ìwọ yóò tọ̀ mí níkẹyìn.”

Jòhánù 13

Jòhánù 13:34-38