Jòhánù 10:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà Jésù tún wí fún wọn pé, “Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, Èmi ni ìlẹ̀kùn àwọn àgùntàn.

Jòhánù 10

Jòhánù 10:1-15