Jòhánù 10:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olè àti ọlọ́sà ni gbogbo àwọn tí ó ti wà ṣáájú mi: ṣùgbọ́n àwọn àgùntàn kò gbọ́ ti wọn.

Jòhánù 10

Jòhánù 10:3-11