Jòhánù 10:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òwe yìí ni Jésù pa fún wọn: ṣùgbọ́n òye ohun tí nǹkan wọ̀nyí jẹ́ tí ó ń sọ fún wọn kò yé wọn.

Jòhánù 10

Jòhánù 10:1-12