Jòhánù 1:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù rí Nàtaníẹ́lì ń bọ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì wí nípa rẹ̀ pé, “Èyí ni ọmọ Ísírẹ́lì tòótọ́, nínú ẹni tí ẹ̀tàn kò sí.”

Jòhánù 1

Jòhánù 1:43-51