Jòhánù 1:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nàtaníẹ́lì béèrè pé, “Násárẹ́tì? Ohun rere kan há lè ti ibẹ̀ jáde?”Fílípì wí fún un pé, “Wá wò ó.”

Jòhánù 1

Jòhánù 1:44-51