Jòhánù 1:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nàtaníẹ́lì béèrè pé, “Báwo ni ìwọ ti ṣe mọ̀ mí?”Jésù sì dáhùn pé, “Èmi rí ọ nígbà tí ìwọ wà lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ kí Fílípì tó pè ọ́.”

Jòhánù 1

Jòhánù 1:47-51