Jòhánù 1:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fílípì rí Nàtaníẹ́lì, ó sì wí fún un pé, “Àwa ti rí ẹni náà tí Mósè kọ nípa rẹ̀ nínú òfin àti ẹni tí àwọn wòlíì ti kọ̀wé rẹ̀—Jésù ti Násárẹ́tì, ọmọ Jósẹ́fù.”

Jòhánù 1

Jòhánù 1:40-49