Jeremáyà 6:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì ń wo ọgbẹ́ àwọn ènìyànmi bí ẹni pé kò tó nǹkan.Wọ́n ń wí pé, ‘Àlàáfíà, Àlàáfíà’,nígbà tí kò sì sí àlàáfíà.

Jeremáyà 6

Jeremáyà 6:11-20