Jeremáyà 6:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Láti orí ẹni tí ó kéré sí oríẹni tí ó tóbi ju, gbogbo wọnni ó sì ní ojúkòkòrò fún èrè,àwọn wòlíì àti àlùfáà lápapọ̀sì kún fún ẹ̀tàn.

Jeremáyà 6

Jeremáyà 6:10-23