Jeremáyà 49:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa Dámásíkù:“Inú Hámátì àti Árípádì bàjẹ́ nítorí wọ́n gbọ́ ìròyìn búburú, ìjayà dé bá wọn,wọ́n sì dààmú bí omi òkun.

Jeremáyà 49

Jeremáyà 49:16-24