Jeremáyà 49:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó! Ẹyẹ idì yóò gòkè fò wálẹ̀,yóò tẹ ìyẹ́ rẹ̀ lórí Bóráṣà.Ní ọjọ́ náà ọkàn àwọn ajagunÉdómù yóò dàbí ọkan obìnrin tí ń rọbí.

Jeremáyà 49

Jeremáyà 49:13-32