Jeremáyà 49:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dámásíkù di aláìlera, ó pẹ̀yindàláti sálọ, ìwárìrì sì dé bá a,ìbẹ̀rù àti ìrora dì í mú, ìrorabí ti obìnrin tí ó wà ní ipò ìrọbí.

Jeremáyà 49

Jeremáyà 49:18-33