Jeremáyà 48:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní abẹ́ òjìji Hésíbónìàwọn tí ó sá dúró láìníolùrànlọ́wọ́ nítorí iná ti jáde wáláti Hésíbónì àti ọwọ́ ináláti àárin Síónì sì jó iwájú orí Móábù runàti agbárí àwọn ọmọ àlùfáà.

Jeremáyà 48

Jeremáyà 48:42-46