Ègbé ní fún ọ Móábù!Wọn yóò sì kó àwọn ọmọkùnrin yín lọ síilẹ̀ àjèjì àti àwọn ọmọbìnrin yín lọ sí ìgbékùn.