Jeremáyà 48:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹnikẹ́ni tí ó bá sá fúnẹ̀rù yóò ṣubú sínú ọ̀fìnẹnikẹ́ni tí o bá jáde sítanínú ọ̀fìn ní à ó múnínú okùn dídè nítorí tíèmi yóò mú wá sóríMóábù àní ọdún Ìjìyà rẹ,”ní Olúwa wí.

Jeremáyà 48

Jeremáyà 48:40-47