Jeremáyà 36:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bárúkì ọmọ Neráyà sì ṣe gẹ́gẹ́ bí gbogbo èyí tí wòlíì Jeremáyà sọ fún, láti ka ọ̀rọ̀ Olúwa láti inú ìwé ní ilé Olúwa.

Jeremáyà 36

Jeremáyà 36:4-12