Jeremáyà 36:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó lè jẹ́ pé, ẹbọ wọn yóò wá sí iwájú Olúwa, wọ́n ó sì yípadà kúrò ní ọ̀nà búburú wọn; nítorí pé títóbi ni ìbínú àti ìrunú tí Olúwa ti sọ sí àwọn ènìyàn yìí.”

Jeremáyà 36

Jeremáyà 36:1-13