Jeremáyà 36:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní oṣù kẹ́sàn-án ọdún karùn-ún Jéhóíákímù ọmọ Jòsáyà Ọba Júdà ni wọ́n kéde ààwẹ̀ níwájú Olúwa fún gbogbo ènìyàn Jérúsálẹ́mù àti fún gbogbo àwọn ènìyàn tí ó wá láti Júdà.

Jeremáyà 36

Jeremáyà 36:1-15