Jeremáyà 31:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“Àyàfi tí a bá lé àwọn ọ̀run lókètí ìpìlẹ̀ ayé sì di àwárí ní ìṣàlẹ̀,ni èmi yóò kọ àwọn Ísírẹ́lìnítorí ohun gbogbo tí wọ́n ti ṣe,”ni Olúwa wí.

Jeremáyà 31

Jeremáyà 31:33-40