Jeremáyà 31:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àyàfi tí ìlànà yìí bá kúrò níwájú mi,”ni Olúwa wí.“Ǹjẹ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò dẹ́kunláti jẹ́ orílẹ̀ èdè níwájú mi láéláé.”

Jeremáyà 31

Jeremáyà 31:29-37