Jeremáyà 31:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọjọ́ náà ń bọ̀,” ni Olúwa wí, “tí wọn yóò tún ìlú yìí kọ́ fún mi láti ilé ìṣọ́ Hánánélì dé igun ẹnubodè.

Jeremáyà 31

Jeremáyà 31:33-40