Jeremáyà 23:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Olúwa wí,“tí Èmi yóò gbé ẹ̀ka òdodo dìde fún Dáfídì,Ọba tí yóò lo ìjọba pẹ̀lú ọgbọ́ntí yóò sì ṣe òdodo àti ohun tí ó yẹ lórí ilẹ̀ náà.

Jeremáyà 23

Jeremáyà 23:3-15